Topic: Bi ewe oju omi l’eniyan se ri
Description: Psa 146:3 Do not put your trust in princes, Nor in a son of man, in whom there is no help. Job 7:17 “What is man, that You should exalt him, That You should set Your heart on him,
/
RSS Feed
Eniyan ko se gbekele,e seun fun ilaniloye ati isiti ati igbaniyanju losose
Opolo yin ko ni doba loruko Jesu
Bi mo se ngbo itan ye ni mo ranti pe ati fi se ere opin odun nigbati mo as ni ile iwe alakobere.Dada Ogbegun
E ku ise o
Daddy, mo ngbadun, no si ko eko nla ninu eleyi Sir. Hunnnnn, eniyan, omo adamo soro. E seun.
Daddy, mo ngbadun, no si ko eko nla ninu eleyi Sir. Hunnnnn, eniyan, omo adamo soro. E seun.
May SOVEREIGN GOD ALMIGHTY richly bless your ministry Sir IN JESUS NAME AMEN.