Ohun Aanu Episode 340
Topic: B’ile ba se ga to Description: Psa. 11:3 If the foundations are destroyed, What can the righteous do?
Ohun Aanu Episode 339
Topic: Bi ipinle ile o ba duro o re Description: Psa. 11:3 If the foundations are destroyed, What can the righteous do?
Ohun Aanu Episode 338
Title: Enikan mbe, Jambata lo nje Description: Rom. 1:28 And even as they did not like to retain God in their knowledge, God gave them over to a debased mind, to do those things which are not fitting.
Ohun Aanu Episode 337
Title: Awon kan mbe, ohun eelo si iparun ni won Description: Rom. 9:15 For He says to Moses, “I will have mercy on whomever I will have mercy, and I will have compassion on whomever I will have compassion.” v16 So then it is not of him who wills, nor of him who runs,...
Ohun Aanu Episode 336
Title: Iro ni, ko s’eni to l’emi meji Description: Rom 9:22 Ǹjẹ́ bí Ọlọ́run bá fẹ́ fi ìbínú rẹ̀ hàn ńkọ́? Tí ó sì fẹ́ sọ agbára rẹ̀ di mí mọ̀, tí ó sì mú sùúrù púpọ̀ fún àwọn ohun èlò ìbínú tí a ṣe fún...
Ohun Aanu Episode 335
Topic: Eniyan meji, kii padanu iro Description: Gal 6:7 Kí a má ṣe tàn yín jẹ; a kò lè gan Ọlọ́run: nítorí ohunkóhun tí ènìyàn bá fúnrúgbìn, òhun ni yóò sì ká.
Ohun Aanu Episode 334
Title: Egbo na, kinni lala-koko-fefe? Description: 1 Tim. 6:9 But those who desire to be rich fall into temptation and a snare, and into many foolish and harmful lusts which drown men in destruction and perdition.
Ohun Aanu Episode 333
Topic: B’idun ba rapala wo’nu ibusun Description: Rom 6:23 Nítorí ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀bùn Ọlọ́run ni ìyè àìnípẹ̀kun nínú Kristi Jesu Olúwa wa.
Ohun Aanu Episode 332
Title: Kokoro to nj’efo, seb’inu efo lo ngbe Description: Psa. 74:20 Have respect to the covenant; For the dark places of the earth are full of the haunts of cruelty
Ohun Aanu Episode 331
Title: Jugbu, ni ojubo t’eja ti so l’odo Description: Gen. 1:31 vAnd God saw everything that he had made, and behold, it was very good. And there was evening and there was morning, the sixth day.
Ohun Aanu Episode 330
Topic: Omode so’ko lu’roko, omode f’ere ge Description: Prov. 26:2 Like a sparrow in its flitting, like a swallow in its flying, a curse that is causeless does not alight.
Ohun Aanu Episode 329
Title: B’eja ba so l’odo, jugbu omi kii da’wo duro Description: Joshua 5:9 And the LORD said to Joshua, “Today I have rolled away the reproach of Egypt from you.” And so the name of that place is called Gilgal to this day.
Ohun Aanu Episode 328
Topic: Onje fun inu, inu fun onje Description: 1 Cor. 6:13 Foods for the stomach and the stomach for foods, but God will destroy both it and them. Now the body is not for sexual immorality but for the Lord, and the Lord for the body.
Ohun Aanu Episode 327
Title: E maa sora fun awon eke wolii Description: Matt. 7:16 You will recognize them lby their fruits. Are grapes gathered from thornbushes, or figs from thistles? v20 Thus you will recognize them lby their fruits.
Ohun Aanu Episode 326
Title: Lasan ko, ni opo ohun to nsele ni duniyan Description: Psalm 37:1 Do not fret because of evildoers, Nor be envious of the workers of iniquity.